Mark 11:1

Jesu fi ẹ̀yẹ wọ Jerusalẹmu bi ọba

1 aBí wọ́n ti súnmọ́ Betfage àti Betani ní ẹ̀yìn odi ìlú Jerusalẹmu, wọ́n dé orí òkè olifi. Jesu rán méjì nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ síwájú.
Copyright information for YorBMYO